O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Obi ati Oti
Orogbo
Ataare
Owo
Akuko adie mejiEyeleMeji
Agbebo adie meji
Epo ati Eko
Ologbo kan
Akuko adie meji
Pepe meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ki etu okara giri
Koru igba aje ki ore
Ko kara giri koru agbon yaba
Ki ojumo otomo arinjo ti ojo
Ki oti mun esere dahin dahin
Sale sale
Adifafun oryunmila
Baba nsawo lo si ode omijo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peirin ajo kan nbe lese eleyi ko rubo kole ba gbayi bop nbe laarin awujo egbere ebo pe yio je ko se aseyori
Ifa ki elelyi o mura dada papa ilu ti eleyi nla tabi ibi ti elelyi ngba won nfi oogun dan won ki oun na ko mun ra dada ki owo won o mon ba te.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
ewure kan fun ifa
akuko adie meji fun EBOeyelefunfun meji
epo ati eko
pelu oti ati obi
owo
Akuko adie meta
Ori ologbo meji
Pepeye meji
Oruko kan
Epo
Obi ati oti
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe gbogbo nkan ti elelyi nse ti koloju yi ifa pe ti o ba fe ki olojutu ki o mon fi oti bio ifa koto se gbogbo nkan ti oba fe se ki oun na si ma mun oti diedie ki o le ba ni aseyori
Ifa pe ibiti elelyi felo ifa pe ojuoguntole ni ifa pe op munra dada ki won moba fi ori tie fo agbon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Agbebo adie fun ifa
Pelu eku ati eja ati
Obi opelu oti ati owo
Epo ati eko
Oruko kan
Eyeetu kan
Alabahun kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Edale ko gba gere
Ose olosun loni aso
Adifafun aniya lorun
Ti oni oun o fo asoOsunni afomon
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe gbogbo nkan ti elelyi ba fe mon se ki o mon ranti awon oku orun re ifa pe awon oku orun re ko pada leyin re nigba kankan ki o mon se sara fun won dada
Ifa ki elelyi olobo
Aje dada
Ifa elelyi nse wahala
Ntori owo pupoju
Kio bo aje dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbo odidi kan
Obi
Oti
Aso tuntun
Akuko adie meji
Epo
Eko
Pelu owoEyelefunfun meji
Ekuru funfun
Ati obi pelu oti
Akuko adie meji
Agbebo adie meji fun ifa
Eku ati eja
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ewe orikika igba ati eyokan
Ao fi se eja ajabori kan lepo niyo
Pelu iyere
Aote iyereosunni (osedi)
AJE
Ewe sinkinrinmindin topo
Iyere aolo papo ao fi se
Igbin apinnu kan lepo niyo je
Ao te iyere soun odu ifa (ose wonrin)
Explore Ifa
Ose Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Irosun Odu.
