O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ose Otua
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni awamiwaja awo oloyo
Adifafun oloyo
To fi orile
Ti nbo ado
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki eleyi
o mon gbokan le
oogun ki o mon seetutudada ki o si mon
bori re dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
kofi eye etu bori
kofi akuko adie meji
kofi agbebo adie meji
eku ati eja
epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ebi npani koni gbere sinsin ninu
Akasu banba ni won fi se oogun re
Adifafun teyin gbiwa
Tin lo ree sanwo onipin lorun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe ki elelyi orubo
isinmin lori gbogbo nkan
tin se wahala le lori if apeetutuni o gba kale
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete kan fun
Akuko adie meta
Eye etu meji
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ajikanse lekun
Adifafun gbogbo okanra irunmonle
Won ngbe EBO lo ode orun
Ajikanse lekun
Adifafun akilolo
Akilolo ngbe ebo lo ode orun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki eleyi
o mon gi EBO se
alo rara ki o tete
mon rubo ti won
ba ti sofun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelefunfun
Pepeye meji
Akuko adie meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Piiti ni ese subu
Alagemo ni oto sele
Oto gele beni koto we sori
Adifafun awurela
Ti n sawo losi ode ijebu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ki eleyi orubo
si ibi ti elelyi nlo ki o
le ba di eni ti won o mon
sare ra oja re ki oja re
mon ba kuta rara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eyelemeji
eyeetu meji
agbebo adie meji
okete kan
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ao toju ewe odundun ao te
iyereosun ni odu ifa (ose tua)
Ao da iyereosunsi ara ewe odundun yi ao soro soke nibi ti ategun oti mon fesi
Explore Ifa
Ose Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ose Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Otura Odu.
