O
Ose Meji in Ifa Divination represents prosperity, abundance, and the rewards of spiritual alignment.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Opole
Ni ko se muluku muluku
Adifa fun won lode ibadan
Nijo ti eranko finfin pawon lomo je
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe irelaiku fun eleyin ki eleyi orubo emi re pe ikankan ni jo eleyin laya ebo ni ko se kole ba di ire
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meta
Opolopo eko
Obi
Epo pupa
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Orofo
Awo won lo de ibadan
Lose fa fun won lo de ibadan
Ni jo ti won ku ni rogba rogba
Ti won ku ni rewe rewe
Bi eni ti won ji oun iku je
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyi orubo laiku pee emi eleyin ebo ni ko se kio si maa lo bo ifa dara dara pelu eran oruko kan.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Sese olonngo
Pirin ebiti
Adifa fun orunmila
Ni jo ti baba omon sowo ijakadi kiri
Kari aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyin ki eleyi omo ja ki o si lobo ifa daradara pelu eku eja abodire kan ki osi fi akuko adire kan rubo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Akuko kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Opole ni ko se
Muluku muluku
Adifa fun won lode ibadan
Igbati won muomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun pe ire omo fun eleyi pe oju omo nip on eleyi ebo ni ko se kio leba di olomon ko silobo orisa ati ifa pelu opolopo igbin.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin merindinlogun
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe aje ewe ominsin minsin gogoro ao wa lo mejeji papo ao wa fi se ekirin eran ewure merindinlogun je lepo ni yo ao se adura si ka toje obe naa daradara.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ewe segunsete ao toju eran esin die ao gun papo mo arawon ao wa po mon osen dundun ni naa fi we ni ale fun ojo meta.
Explore Ifa
Ose Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori, Ose Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Meji Odu.
