O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni Ise o mo ori olu
Osi o mon eni olawo lara
Agadangba o mon oju
Eni ti oro oun
Adifafun eni ti aye nbuku
Ti elefumare o mon bukun
Aje ifa o to gege jaye oyemi
Ju tegbemi lo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki elleyi olomojuto ifa dada ifa ni yio je ki oniyi lawujo gbere ki omon fi ifa sere
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Yio fi elede bofa
Yio fi oruko rubo
Yio fi eyeetu bori
Epo
Eko
Obi
Oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ise o mon ori olu
Osi o mon eni awo
Agada ngba o mon oju
Eni ti oro oun
Adifafunogunti o tida
Bako ti o fegayo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ki o lo bogun dada (aja)
Akuko adie
Epo
Eko
Eyeetu ni ori gba
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ogbogbo ajanku
Ni ogbodo mira jigi
Loju asa ode
Adifafun oba
Oba nsunkun pe apa oun
Ko kaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire isegun Fun eleyi ki orubo isegun pelu awon ti ngb eogunti gbogbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Agbebo adie meji
Fun ifa pelu
Okete kan fun awon
Agbalagba
Oruka owo
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ikenike soko
Monba ni mon ba toro
Adifafun olu
Njoti afomi oju sogbere
Ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi
Oru bo ntori ire
Gbogbo
Ifa pe ire gbogbo won
Eleyi korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemerin
Agbebo adie meji
Akujko adie meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ori oka kan
Ori re kan
Lekeleka kan
Ao jo pelu atare kan
Ati ewe sefunsefun
Ao lo kun na daa (ose ogunda)
Explore Ifa
Ose Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Ogunda Odu.
