Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ose Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ose-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ti o bam on ise je Ko mon je onise Bi osi mon ise ko mon Je oluse Opnise lo wumi o luse osuhan Adifafun oosala osere mongbo Yio ran eja ati akan nse Nje ise ti aran lo je re Ise aran eja ran akan Akan nikan lojise rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elelyi O rubo lori eyan meji Ti won jo nsise kan naa Ki won orubo sibe dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie metaEyelefunfun meji Pepeye meji Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni alanga jija Adifafunesu odaraTi ofise babara sile Ti o mon lo sise oni se

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elleyi orubo ki osi mon fi liana babara sile lori gbogbo nkan ti ba nse

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko fun esu Eyeetu meji Pepeye meji Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Mo sapamon sapamon Ori mi ko sapamon Morin ni koko rin ni koko Eleda mi orin ni koko Adfifafun adaba susu Ti nfomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ki elelyi orubo nitori omo ki osi mon se aigboran si nkan ti won ba sofun ifa ni npa liana awon onbi re niyio ti di olomo laye

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie mejiEyelefunfun meji Akuko adie meji Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni ose wiri wiri Babalawo ewiri Adifafun ewiri Ewiri nlo si agbde

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elelyi orubo lori ibi tin lo ki ole badi eni iyi nibe ki aye sile gbatie dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Awo ewiri Akuko adie meta Eyeetu mejiEyelemeta

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori eyeetu ti abafi bori odidi atare kana o jo pelu yepe idi esu ao te ni odu ifa (osedi) aio so isure si dada ao fi sin gbere si aaarin ori de ipako ao po iyoku mon ose dudu ao fi lemeta ni ale ti aba fe sun

Videos

Watch Ose Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Ose Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ose Iwori Odu.