O
Oturupon Meji in Ifa Divination represents endurance, learning from past experiences, and the consequences of unchecked actions.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Bimoseferin ni mo fe ki ore mi o ri
Adifa fun olomon ateni ore kore
Igba ti n tode orun bo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire iyin fun eleyi ki eleyin osibo orire nitori agbega kio si feran omo lakeji re gege bi tarare.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Bebe okehin
Bebe oke ohun
Adifa fun oturu
Ti o pon meji lekan
Ao toju erupe yaya ogan ao toju ewe awede ao wa mon ose dudu ao wa fi omi agbon po titi ti yio fii de ao wa mon fii we.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun ire omo fun eleyin pe oju omo nip on kolo boo sun pelu adire agada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adie meji
Akuko kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Akara ni ko kuta lojude opon
Adifa fun ayinrin
Ti se omo won lojude iwoya
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo isegun pe awo kan ni won gbo ti eleyin ebo ni kose.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Pepe lawole
Atita lawo ode alapanu dede
Lokole tan lokoju re si gbagedeolofinBeni kofin kan omi beni ko fi kan oke
Adifa fun oyepolu
Ti se omo isoro nife
Baba re ku
O fi sile ni leunje leunje
Iya re ku ofi sile ni lenje lenje
Won wa ko ohun oro le
O bu puru sekun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyin orubo isegun ki osi lobo awonolorunre dara dara kio si rubo pe ohun yio ba segun ki osi lo bo ifa pelu eku eja adire eran ewure.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Ewure kan
Epo
Eko
Obi
Oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao mu ewe segun sete pelu ewe alupaida ao gun mon ose dudu ao wa fi maa we fun ojo meje.
AWURE
Explore Ifa
Oturupon Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Oturupon Ogbe,Oturupon Oyeku,Oturupon Iwori,Oturupon Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Meji Odu.
