O
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oturupon se
Awo eja losefafun eja
Nijo ti momi oju sogbere omo
ao toju ewe emini ewe sefun sefun ao wa fi se eyin adire meje lepo ni yo ao wa ta oyin die si
ti obe naa baji naa ao se adura ao wa koje lese kese
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pere omo fa eleyii
pe oju omo n pon elelyii ki o lo bo
ifa leku leja labo die yio bimon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodire kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oturupon da seke
Obadade owo
Oturupon n daseke
Oba tepa ileke
Oturupon daseke
Abada buro oje
Adifafuniyalodeipo
Eyi ti yio lewure daran daran nile
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun fun eleyi
ki eleyi olo fi ewure ti enu rwe ba funfun ifa kio si loru bo fesu pelu akuko adire
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oturupon dasedase
Adifafun ase bagebage
Ti moni opju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire omo fun
eleyi ki eleyi orubo omo
pe oju omo nip o yio lobo
ifa pelu eye pepeye meji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi pe awon kan ni won omon ba fi ori
gbari korubo ki ore wo oleba di tie ki ole fi ewure bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
inu enure ao wa lopo ao wa o mon ose dudu ao wa fi we fun ojo meje
Explore Ifa
Oturupon Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Oturupon Meji,Oturupon Ogbe,Oturupon Oyeku,Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Ose Odu.
