Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Owonrin Irete

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/owonrin-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrin yanrete rete rete Adifafun Aje Ti n tode orun bowa sile aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere aje fun eleyii, pe aje n bow a joko sile eleyii, pe ebo ni ko ru pe yoo nire aje.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Obi meji Oti Epo Eko Agbado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Mantala man eekan laawi Adifafun Owonrin Ti o yan rete laso

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o ru, ki o le baa ri ire naa gba, pe aso kan nbe lorun eleyii ti o wow a dafa yii pe ki o ma wo ma, pe awon aye ti dawo te.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Ase eleyii to wo Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Owonrin Yanrete Rete Rete Adifafun aje Ti n tode orun bow aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore aje fun eleyii, ifa ni aje n bo fun un pe aje bo wa joko sile re pe ebo ni ko ru.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu Obi meji Oti Epo Eko Agbado Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Owonrin yanrete rete rete AdifafunOrunmilaBaba ji Baba o lowo kan aayona

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eleyii, pe ebo ni ko ru, ifa ni o n saroye pe oun ko lowo lowo, sugbon ebo ni ko ru, yoo di olowo repete.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo die kanEyelemeji Epo Eko Agbado Owo

Videos

Watch Owonrin Irete teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Ogbe,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Irete Odu.