O
This Odu represents the need for careful planning and strategy.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin palaba ipabo
AdifafunoluweriTi be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ota po fun eleyii, ko rubo yoo pada wadi eni ti aye o maa warifun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adie kan
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Owarin Babalawo gbaro
Lodifafun Gbaaro
Igba tin be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyii n lo ibi kan ti awon ota si ti rona dee, pe ebo ni ko ru ko le ba a ni iseguns
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemejia
Akuko adie kan
Abodie kan
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owarin lawo inun omi
Olobara awo ale odo
Adifafun Ondese adi omo ola kan diran nile wa Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Ko e pe o
Ko e jinna
Aje wa jede tuturu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire ola fun eleyii, pe ki o rubo nitori ola ati wipie iran eleyii olowo ni won je.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Owonrin lawo olobara
Awo sereyo
Adifafun Sereyo
Ti n fomi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo, pe owo eleyii yoo po, yoo si di eni taye o maa pesin.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo eree
Abodie meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Owonrin Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Ogbe,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Obara Odu.
