O
This Odu signifies the importance of vigilance and awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oyin mele awo aseyin nin mokin
Adifafun aseyin mokun
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ibi kan ni eleyii n lo, pe ota po nibe, ko rubo aarin ota naa ni o wa, pe aarin ota naa ni eleyii o ti doba.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyin Epo
Akuko adie kan
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oninle ni nko wiyo kalejo
Otowiyo adifafun Ogo ti n rele iseyin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ibikan ni eleyii nlo, pe korubo, ko si ma maa koko soro ninbe ki won o ma baa somun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo iyo
Epo
Eko
Owo
Agbado
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oro dunmin joloro
Adifafun Osi efa
Ti n sawo rode Oyo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyii yoo la lati ipase oba, ko si maa ko egbin kire ola naa o le e too lowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kanEyelemeji
Epo
Eko
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Explore Ifa
Owonrin Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Ogbe,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Osa Odu.
