O
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin baje lese
Ariwo yee, ariwo yee
AdifafunOrunmilaBaba n be laarin ota meta
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo pe eni ti eleyii n fi oro re lo naa ni ota re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie kan
Obi meji epo
Akuko adie kan
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Awoka woka igbin
Awoka woka ikarahun
Adifafun Ikakara
Ti won ni ko ni pe lodo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo pe ibi kan wa ti won fe lekuro ni n be korubo kii awon ota o maa baa le eleyii kuro nile
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ikarahun igbin
Akuko adie meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ajenje adifafun Eeyan
Ti n seru ipin loru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii pe ki o rubo, ko sib o ori re pe ori ola ni o yan lati ode orun, pe ko rubo orire yoo sile kun ola re fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Eja mejiEyelemeji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Agbon meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kokan sagba
Isagba ni duuru
AdifafunOrunmilaIre aje n lo lode okan kan o yale
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii, ifa ni ebo ki ire eleyii o ma baa se koje re ni ko ru, ki ire aje o le yaw a fun un.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Abo adie kan
Obi merindinlogun
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Owonrin Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Ogbe,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Oturupon Odu.
