Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Irosun

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Íròsùn Excerpt
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-irosun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Igi nla yoninju Ojue tole kokoko Adifafun eegun abufun euru Igba ti won jo n sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o soro pe ota nla kan ree fun eleyii, ota yii ju eleyii lo, pe korubo ko si ma jaya pe yoo segun eni naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ekuru funfun Eyele funfun meji Abo adie Eku meji Eja meji Epo pupa Eko Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Pamansiki adifafun boti Ti n gbogun lo ilu ajarun Oyeku rusu rusu Adifafun won legba eesu Nibi won ti nkori aje jo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo pe won o fi eleyii se olori kan nibe pe ibe si ni eleyii yoo ti di olola laye re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo oka baba Akuko adire kan Epo pupa Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyengbosun Adifafun aje oun omo Won jija agba nile Olodumare

Videos

Watch Oyeku Irosun teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Irosun Odu.