O
This Odu signifies a period of transformation and overcoming obstacles through perseverance.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Olowo ni n fa oko olofa aferu
Iwo o raala
Emiin o rala
Aroko man rala lodija sile
Adifafun oyeku okanran
Igba ti won n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oko iroko kan
Akuko adire kan
Epo eko
Agbado ati Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oyeku olokanran kan Babalawo
Awo lodifafun awo tii sore oman
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ore eleyii kan niyii ti yoo ta eleyii nijanba, pe ki eleyii o sora fun un ore naa daa daa kosi paaro aye ibi ti n sun, ko ma sun ibe fun odidi ojo meje.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aso eni yii ti o ni awo meta
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Atawin opele awo won niragbiji
Adifafun won niragbiji
Nijo ire won n silo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire eleyii ti silo sugbon korubo pe ire re n pada bow a joko ti pada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Alabahun kan
Akuko adire kan
Epo pupa
Agbado
Opolopo owo
Omoagbarato n san
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Gbongbo sigila awo ile alase
Adifafun Alaase abu fayare
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyii yoo la, pe ko si rubo fun iyawo re naa nitori
won yoo jo la lasiko kan naa ni
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ako pepeye kan
Epo pupa
Eko
Agbado
Opolopo owo.
Explore Ifa
Oyeku Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Oyeku Meji,Oyeku Ogbe,Oyeku Iwori,Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Okanran Odu.
