Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Obara

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Óbárà Excerpt
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-obara
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyeku faba goke baba lawooluweriAdifafunoluweriIgba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni laarin ota ni eleyii wa sugbon yoo rubo kole baa ni isegun jale tan lowo awon ota re. Ifa ni ore kan niyi ti oun ati eleyii jo n rin, ifa ni kee sore re, ko si mo maa so oro re fun un mo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie Akuko adieEyeleEpo pupa Agbado Opolopo owo Eye etu Opolopo owo Epo pupa Eko Agbado
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Agbori odidifa agbaja sapele Adifafun eeman ajala Ti o nire gbogbo juwon lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ore kan niyi ti oun ati eleyii jo n rin, ifa ni kee sore re, ko si mo maa so oro re fun un mo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu Opolopo owo Epo pupa Eko Agbado
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku palaba ipabo sagodogba Eluju eluju isagodo gba ipara AdifafunOrunmilaIre gbogbo nlo nita Okankan o ya le wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni kele yii o rubo pe yoo ni owo lowo ju awon eeyan re yoku lo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kanEyelemeji Epo pupa Eko Agbado Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oyeku palaba ipabo sagodogba Eluju eluju isagodo gba ipara AdifafunOrunmilaIre gbogbo nlo nita Okankan o ya le wa Ebo ni won ni kifa o se O si rubo nibe Ero ipo Ero ofa Aje wa jede tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire lati okere fun eleyii pe ebo ni ki eleyiii o ru pe yoo nire gbogbo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie kan Eku meji Eja meji Eye etu Epo pupa Eko Owo Agbado

Videos

Watch Oyeku Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Oyeku Meji,Oyeku Ogbe,Oyeku Iwori,Oyeku Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Obara Odu.