O
A short interpretation of Òyèkù Òtùrùpòn
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oyeku baturupon
Ire gbogbo womun lapo odiwomun
Lapo ire gbogbo
Adifafun bata ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pere isegun ota fun eleyii, pe oore eleyii kan n be ti won jo maa n se wole wode ko sora fun ota gidi nin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ekuru funfun
Obi
Akuko adire meji
Epo
Eko
Agbado ati owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Wondagba nile olufon
Won lulu kan gidigidi lakodijesa
Adifafun Olodumare
Omo ateniola fori sapeji
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo, pe awon ota kan ree ti won fowo bo irawo eleyii ko rubo ko lee baa segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aso dudu
Aso funfun
Aso ayinrin
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oyeku baturupon aringindinwin
AdifafunOrunmilaBaba n sunkun alairejemun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire aje n bo feleyii sugbon ko fi ewure bofa kaje eleyii o le baa de
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure
Obi
Oti
Akuko adire kan
Abo adire kan
Epo
Eko
Agbado ati owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Olukowko jikonko
AdifafunOrunmilaNijo gbogbo ire nlo, okankan o yale
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire n koja eleyii sugbon ire naa ko te eleyii lowo, ko rubo, kore naa o lee too lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Elede kan
Obi
Oti
Akuko adire kanEyelekan
Abo adie kan
Epo
Eko
Agbado ati owo
Explore Ifa
Oyeku Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Oyeku Meji,Oyeku Ogbe,Oyeku Iwori,Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Oturupon Odu.
