I
This Odu signifies the power of patience and strategic planning in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Moduro owo mi oto isin
Mobere owo mi oto isin
Awon agba kan agba kan
Won ni ki n dubu yeke
Isin wo simi lenu
Adifafun ejika gogoro
Ti ogbe awo dide
Awon ni o gbe awo dide
Ejika gogoro ni ogbe
Osun de igbo
Awo ni o gbe awo dide
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ni ti osun mon eleyi ni yio saanu re ifa pe ki eleyi o sirubo nitori aare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Eyele meji
Epo
Eko
Akuko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Afa obe la fi owo
Nu opo opo ori eni
Ti yo ro fun
Adifafun oti minhinminhin
Igbati nfomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo ntori omo ki agan tin be legbe eleyi orubo nitori omo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie merin
Akuko adie merin
Obi
Oti
Eku
Eja
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi osebo aare ki o mon ba dubule aare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Pepeye meta
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
1ISEGUN
Ewe segun sete ewe ijaoke ao gun papo sususu aolo imin orun aopo papo mon ao fi eeru si ao mon fin ni turare.
Ewe sefunsefun aolopelu iyere ao fi se eyin ororo mefa lepo niyo ao wsa te ifa ika olosun ao se adura si dada ao wa je gbogbo re lori en tuntun.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe segun sete ewe ijaoke ao gun papo sususu aolo imin orun aopo papo mon ao fi eeru si ao mon fin ni turare.
Ewe sefunsefun aolopelu iyere ao fi se eyin ororo mefa lepo niyo ao wsa te ifa ika olosun ao se adura si dada ao wa je gbogbo re lori en tuntun.
Explore Ifa
Ika Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Irosun Odu.
