I
This Odu represents perseverance and the resilience needed to overcome obstacles.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE KINI 1
Kala nkan di
Adi kaka wolu
Adifafun orunmila
Baba ngbogun lo si ibi atoketodoke
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ibi ti eleyi nlo yi if ape ogun nbe nibe fun ifa pe korubo lo kole ba segun bo ibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Akuko adie meta
Agbebo adie meji
Eku
Eja
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika dindi awo erin
Adifafun erin
Ika dindi awo efon
Adifafun efon
Awon ko niyi ebo
Igbati won sunkun pe awon ko niyi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki awon omo iyameji tabi ore meji ko rubo ki won o le ba gbayi nibi ti won ban lo tabi lori nkan ti won ba dawo le
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele merin
Pepeye merin
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
1ISEGUN
Eeso lowerenjeje eyo meje ao lo pelu eyo atare meje ao lo ti o kunna dada ao wate ni ikadi ao so gbogbo nkan ti aba fe ao wa fi sin gbere si orikerike ara
Explore Ifa
Ika Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Odi Odu.
