Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Ika Iwori

Ika Iwori also known as Ikawori
Aliases: Ikawori
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ika-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ikawori

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE KINI (1) Ika fefe lafoye Iwori fefe lafogba Adifafun ewiri ti se obinrin Ogun Igba ti n fomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori omo ki o lobo ewiri agbede pelu akuko adie ati obi pelu oti

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meta Agbebo adie meji Eyele funfun meji
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni poki are de o Ojonleke Adifafun orunmila Baba o fi oro gbogbo se erinrin Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje poki are deo Ojonleke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon mon binu si gbogbo oro ti won ba so fun ki nkan re ole mon da.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meta Akuko adie meta Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

(3) Ikafefe la foye Iwori fefe la fogba Adifa fun oniyan hanyan Ti ntorun bow a saye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o lobo ori re dada tio ba si ti ji ko mon sure fun ori re larolaro ko mon toro nkan to ba fe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etumeji Pepeye meji Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

(4) Ika fefe la foye Iwori fefe la fogba Adifafun agidingin Ti won n ran se ilku pe lorun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori iku ko fi eyele merin se irapada emi re nipase alakala ti n la

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin Ko fi igbin bo orisa Akuko adie meji Agbebo adie fun

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe okirika merindinlogun ewe tete adayeba merindinlogun eyo iyere merindinlogun aolo papo ao fi se eyele ti a ge si merindinlogun je ao tee fun ni odu ifa ikawori ao se adura si ao ko je pata pata

Videos

Watch Ika Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ikawori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Iwori Odu.