I
This Odu signifies the journey of perseverance and strength in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ika kankankan
Bi ina eyin
Olakanran kankankan
Bi oorun owuro
Adifafun ijobiona
Tii se ojise irunmonle merindinlogun
Eyin ijobi ona bi eba la tan
Kemonse gbagbe awo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope oun pe ire ola fun elelyi amon ki eleyi omo Se okanjua ki ire naa ole to lowo
Kio si fi akuko adire rubo pelu aso ododo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Aso ododo
Eko
Epo
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika kankankan
Babalawo agogo
Adifafun agogo
Agogo nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa sope oun pe ire iyin fun
eleyi pea won meji kan nu
ti won ojodASE po ki won orubo
ki aye ole bayewon ki won osi fi pepeye bo ori won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Epo
Eko
Oni
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ika kankankan biina
Eyin
Olokanran kankankan
Bi oorun awuro
Adifafun ode ode nsawolo
Igboje eluju je
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire gbogbo fun ore meji pe ki won orubo ki ire ole batewon lowo ki won ofi ewure bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Okanran koro kara
Adifafun ikakara
Abu feja
Nijo ti won gbogun lo ilodo
Ebo ni won ni kiwon ose
Won gebo ni be won rubo
Nje, ikakara
kosai beja gbodo ikakara
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa so pe ire isegun fun eleyi ki elleyi olobo ori re pe awon kanni won fe gbogun ti elelyi ebo ni koru ko fi eyetu bo orire kio fi akuko rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyetu kan
Akuo adire kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe ina ewe esinsin awo ilu ao wagon mo ose dundun ao wa lotoju okusu are ao wa fin po ose naa ao wa maa we larolaro.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ori eye etu ati ewe tund e ati egbo re ao Wa jo tio bajo tan ao wa fi si gbere si orun owo Ati oru ese ao wa fi iyo Ku fo eko tutun mu.
Explore Ifa
Ika Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Okanran Odu.
