I
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ebo ni won ni kose Igba aisebo
Igba aise etutu
Eyin o ri ifa awo ki biti nse.
Ifa de alase ope abise wara wara.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
If ape ki eleyi o rubo ko mon badi eni ti ko ni begbe pe lasiko ti gbogbo egbe re ba nwulo ko mon di eni eyin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo Igbin
Alabahun meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Polo Itakun
Abisun mon lese
Jangele jangele
Adifafun oninu ire
Ti won o mon fi ojojumon aye fi esan ika san
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe gbogbo nkan ti eleyi nse gege bi oore ika ni won fin san lesan korubo ko le ba jeer Iwa re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Eyele meta
Igbin meji
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni akase akase
Akase radarada
Adifun ase oun
Agbon njo ti won
Jija agba nile eledumare
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo lori enikan ti oto ti ongbogun ti nba jija agba ki ole ba segun eni naa
Ifa pe ki eleyi o rubo ki gbogbo ogun ti nja o le ba se danu patapata ifa pe omo iyare na fun
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
omundun enu opiye mesan eepo obo ao gun papo mon ose dudu ao ko sinu eepo iginla ao mon we ni aago kan oru ao te iyere osun ni odu ifa (IKA OSE)
Ase aduro si dada ni igbati aba te odu na tan ao po mon ose na ao mon buwe pelu kanhinkanhin tuntun
Explore Ifa
Ika Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Ose Odu.
