Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Ika Obara

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the balance between wisdom and action in decision-making.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ika-obara
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni ka ka bara Kakura nbe Adifafun iyan Iyan nraye apinje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o rubo apesin ki ole ri eni pesin ki osi mon yo ayoju Ki eleyi o mon yo ayoju lori nkan ti oba nse ki o si gbo ikilo papa laarin awon ti oba wa Ki eleyi orubo nitori omo ni o ki osi mon se aigboran ki araye o mon ba mon fi tipatipa aba Omo lowo re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meta Eyeetu meji Akuko adie meta Epo Eko Eran agilinti Akuko adie meta Epo Eko Agbebo adie meta Eku Eja Epo Eko Obe tuntun Kunmon
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ikabara geti Adifafun odan Odan nroju ode

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon yo ayoju lori nkan ti oba nse ki o si gbo ikilo papa laarin awon ti oba wa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agilinti Akuko adie meta Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ikabara ikabara Ikabara geti Adifafun bara Ti nloko ailero lodun Ebo ni won ni ko mon se Igbatu ebo igba aity eru Eri ifa awo ki biti nse Ifa de alase ope abise warawara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori omo ni o ki osi mon se aigboran ki araye o mon ba mon fi tipatipa aba Omo lowo re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meta Eku Eja Epo Eko Obe tuntun Kunmon

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori eye etu meta eku asinrin kan odidi atare meta ewe rekureku topo dada ao jo papo aolokun na afeni odu ifa Aso gbogbo nkan ti abafe ni isegun si ao ro sinu ato kan ao mon fi foko tutu mon larolaro idire ko gbodo kanle mon o Ewe aje ao lo pelu iyere ao fi se eyele funfun kan lepo niyo ao te iyere osu ni (ika obara) AJE Ewe wonjo pupa aolo pelu iyere ao fi se igbin apinnu meji lepo niyo ao te iyere osun ni IKA KANRAN ao se adure si ao keje

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ori eye etu meta eku asinrin kan odidi atare meta ewe rekureku topo dada ao jo papo aolokun na afeni odu ifa Aso gbogbo nkan ti abafe ni isegun si ao ro sinu ato kan ao mon fi foko tutu mon larolaro idire ko gbodo kanle mon o Ewe aje ao lo pelu iyere ao fi se eyele funfun kan lepo niyo ao te iyere osu ni (ika obara)

Videos

Watch Ika Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Obara Odu.