Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irete Meji

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Irete Meji in Ifa Divination emphasizes justice, balance, and the inevitability of cause and effect.
Listen
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irete-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ateyin ayinte Adifa fun Elede Tiise yeye odo Igbati mo mi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire omo fun eleyi pe oju omo n pon kio pa afiju ti kio le badi olomo laye kio si lo bo ifa pelu elede kan.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi elede kan Akuko adie kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Poro bayin Ala bayin Adifa fun ladebu Tii se yeye oke Igba ti momi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi pe ebo ni ko se pe ki eleyin osi mon bawon ja sinkan ogun tori ohun naa ni yio pada to si kio lobo orire pelu eye etu kan kio si fi eye etukan rubo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ore oo Ko re mi Adifa fun ire Ti lolete meji lodo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyi orubo pe ara ko ro eleyin fun ire gbogbo ki eleyi olote ifa ki ara ole baro

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji Eja meji Abodie meji Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ero yanuu fodo kete Adifa fun atoka Ti se ilari olodumare Igba ti mo mi oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi ki eleyi olodi mon ifa daradara pe eleda re ki ro ko ki yenaa ise ijoko ni eleda re mon se kio bo ifa pelu ewure.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe ominni ao wa lopo mon iyere ao wa fi se igbin merin lepo ni yo ao wa se adura si eni naa yio je obeyin. ISEGUN ESE AKOSE KEJI Ao toju ori igbin ao toju ewe apada ati atare kan o wa jo po ti obajo tan ao wa fi sigbere igba ati eyokan si aarin ori, ao fi iyokun fokomu lekan soso lori odo.

Videos

Watch Irete Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori, Irete Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Meji Odu.