I
This Odu emphasizes the need for thoughtful decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ogunda
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Awon meji kan ni won jo n sota yii, sugbon keleyi orubo yio segun nitori ota eleyi to bi ju lo sugbon yio segun re keleyi o si boogunagbede obi ni yoo fi bogun agbede.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Eworo isan
Eworo atori
Adifa fajiga lorun
Tii sobinrin aaye
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Obinrin eleyi ni keleyi o rubo fun ki won ota oman pa ni tori iyawo eleyi ni ota pupo ota ti moun wi yi lati idile obinrin naa ni won ti le wa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Pankere wobo
Wobo pankere
Adifa fun enlojo obo
Ti n loko ailero lodun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ibikan lawon eleyi n lo, ki won o orubo, ki won o to lo won yoo la bo ibe, won o fi opolopo agbado kun ebo won ru, ki won osi man jara won niyan, ki ire won oman ba fo won ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
OwoEyelekan
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, ko si se aase onje oti fun awon awo kire aje eleyi ole to lowo, odo eeyan nla kan leleyi n lo yii, yio rire munbo, eni nan tin damu lori ikan re kan, sugbon eleyi ni yio ba soro re dayo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi opolopo onje obi oti bo ifa
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Egun igbago opolopo isu eminan ikoode kan odidi atare kana o jo po ao man fi epo pupa la lale sun
Explore Ifa
Irete Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Ogunda. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Ogunda Odu.
