I
This Odu highlights the importance of adaptability in navigating challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Osa
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Arote sa
Arote sojo
Arote pakube kube
Adifa fun okete oun efon jo n sota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ota kan ree tolagbara ju eleyi lo korubo yio segunre ko si boegbere, awon egbere ni o baa segun Ota re naa, kosi dimo ifa daa daa ko mon bo fa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Akuko die kan
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Arote sa
Arote sojo
Arote pakube kube
Adifa fun enlojo opolo
Won o jin sofin omo araye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon ota ti gbe koto le de eleyii, korubo ko man baa jin si ofin ota, ko si bo orisa nitoriogunkan ni bo fe leyi orisa ni yio ba segun to ba segun nan tan ko man gbagbe oosa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi, ibi kan leleyin lo yii, yio ri aje mun bon in be, eeyan nla ni eleyi nlo si odore, pe lati ipase eeyan nla na oun nan yio di eni ola.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
OwoEyelekan
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Arote sa
Arote sojo
Arote pa kube kube
Adifa fun oosa nla oseremogbo
Nijo ti n fomi oju sogbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe keleyi orubo ajenbo feleyi, keleyi o fi etu bo fa kire aje ole de fun ko sibo orisa nitori orisa lo un dako ire aje re wa fun oju aje tin pon eleyi lo do orisa ni re re wa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Etu
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori ikun kan ori sebe kan ori elulu kan odidi atare kana o jo po man fi fo ko mun
Explore Ifa
Irete Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Osa. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Osa Odu.
