I
This Odu highlights the need for patience and perseverance.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Otua
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Petenbole Okirini Kisi
Ka susu oo le kafi disa eera
Adifafun ijimere
To oun aaya jo n sota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, ko si bo eegun pe eegun ni o ba eleyi segun ota Ore eleyi kan si ree ti won jo n sore, ko sora fun ore naa nitori ore naa yio gbabode fun ko si ma maa so oro enu re fun eleyi tan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
A o fi eko olele, obi, ati oti bo eegun.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Eti erin ni odojo poju erin
AdifafunorunmilaBaba n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
A da taka agbigbo
Adifafun igunnugun
Omo agbelu jofe
Igba ti n tomi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, eleyi n se wahala kotori Owo sugbon korubo ko ni se wahala mo koto ma n rowo sele aye omoorunmilani eleyi ise awo leleyi yio se to yi o fi da
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Etu
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Pepele ni ogbeleji
AdifafunorunmilaBaba o fowo adugbo se tie
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo pe ire eleyi n be ni to si ire kire re ole te lomo keleyi osi ma n ma n se ahun ko si dimo oun ifa daada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori ikun meji ori alegba meji ikoode meji odidi atare kan a o jopo oyin la o ma n fi laa laaro laaro
Explore Ifa
Irete Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Otura Odu.
