I
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ofun
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Tefun Tefun Kanrandaa
Adifafun fagbaa rin
Ti n be lawujoeleye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Aarin ota ni eleyi wa korubo, yio segun aarin ota na ni eleyi yio gbe titi yio fi segun awon ota o sini lefi eleyi se nkan kan, awonu ni won o maa wo eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Atefun yigi yigi yigi yigi
Adifafun ori
Ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, ko si bo orire, ori eleyi ni yio ba eleyi segun pe aye n da eleyi laamu, gbogbo igba lawon ota n ba nkan eleyi je eleyi o wa rubo yio segun ori eleyi si duro tiiolorunoba segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Tefun tefun kanranundan
Adifa foba
Adifa fun akapo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire ola fun eleyi eleyi yio la lati pase oba tabi eeyan la sugbon keleyi o ma n lafojudio nitori ola eleyi yio po ti okiki re o si kan laarin ilu.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Tefun tefun kanrandan
Adifafun aniya lorun
Igba ti n fomi oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere aje lati okeere fun eleyi keleyi rubo ko si fi ekuru funfun bo aje ati ori ko si fi eku emo bori iyare ati aso funfun ko si ma n toju iyare dada nitori ori iyare ni yio laa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Eku eman
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ewe alupaida eeku ijebu eeru alaman iha eeso alu gbanko ao jo gbogbo re po ao man fi fokomu
Explore Ifa
Irete Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Ofun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Ofun Odu.
