I
This Odu emphasizes the importance of strategic planning and thoughtful decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Oturupon
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ka Dan tutu
Ka te n tutu
Ka fefefe o fe si ko le gbaale gbaale bio ta
Adifa fun tete rogbodo
Tii somo kunrin ode
Igba tin be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni laarin ota lele yi wa awon otan ba unkan eleyi je korubo ki won olee ma n ba nkan re je ma paapaa julo bi eleyi se n gbiyanju bee, lawon ota si tun n ba nkan re je keleyi orubo kole ba segun awon ota re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ka da n tutu
ka te n tutu
Kafefe ofesi
Kole gbaale gbaale bi ota
Adifafun sigidi
Tin be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon ota re fe pa eleyi sugbon ifa ni keleyi odi mo ifa ni o ba segun ko si fi sigidi meji rubo kosi maa maa sare soro lawujo nitori wipe won n so eleyi dada. Korubo kole baa segun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Alabahun kan
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
OsunSun Gban Gidi
Atare gban gidi
Adifafun gbedu
Ti n lo aafin osan gan gan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, won o wa pe eleyi nibi kan ko ma n wipe oun olo o yio labo latibe ni eleyi yi o la lati pase oba yio di eni ti aye o ma n wari fun keleyi o si fun awon onilu gbedu lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
AgbadoEyelekan
Owo.
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ka da n tutu
ka te n tutu
Kafefe ofesi
Kole gbaale gbaale bi ota
AdifafunorunmilaIfa n n lo lee te ire lodo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi otefa ka je re ole bade, ifa ni ara oro eleyi sugbon korubo ara yio ro eleyi faye tabi lodo Ifa loore eleyi wa keleyi o wa lo tefa kara ole baa ro fun aye.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ison sori isu odidi atare kana o jopo a o ma n fi foko mu
Explore Ifa
Irete Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Oturupon. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Oturupon Odu.
