Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ogunda Irete

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for patience and perseverance in achieving success.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ogunda-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ogunda kete penpe Adifafun orangun mojo Ti o joye ti o ju babare

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Awon meji kan ni won jo n sota yii, sugbon keleyi orubo yio segun nitori ota eleyi to bi ju lo sugbon yio segun re keleyi o si boogunagbede obi ni yoo fi bogun agbede.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ogunlode popo iko Lorawo agada ibeje ibeje Adifafun ajayi Ti won ni ko ni joye amodun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Obinrin eleyi ni keleyi o rubo fun ki won ota oman pa ni tori iyawo eleyi ni ota pupo ota ti moun wi yi lati idile obinrin naa ni won ti le wa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Agogonla abi enu gbaagba Adifafun elewi Ti n sogbogboaruntin nirakaka alailedide Kabojuju kaitele jujo Omo elewii obojuju telejuju omo elewi ni O bo bata tele fijuju le omo Elewii ehoro omo elewi ni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ibikan lawon eleyi n lo, ki won o orubo, ki won o to lo won yoo la bo ibe, won o fi opolopo agbado kun ebo won ru, ki won osi man jara won niyan, ki ire won oman ba fo won ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado OwoEyelekan
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kenu momonu Kete momo ete Ni koran beke Adifafun ehoro tii se wole wode orisa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ko si se aase onje oti fun awon awo kire aje eleyi ole to lowo, odo eeyan nla kan leleyi n lo yii, yio rire munbo, eni nan tin damu lori ikan re kan, sugbon eleyi ni yio ba soro re dayo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi opolopo onje obi oti bo ifa

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Egun igbago opolopo isu eminan ikoode kan odidi atare kana o jo po ao man fi epo pupa la lale sun

Videos

Watch Ogunda Irete teachings on our channel.

Explore Ifa

Ogunda Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Ogbe,Ogunda Oyeku,Ogunda Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ogunda Irete Odu.