O
This Odu represents the balance between wisdom and action in decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ako garun gase
Adifafun osin gagara
Ti n lo le weri ola lodo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Eyan osi mo aye domi
Adifafun Osin gagara tii se olotangun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa fore fun eni to da ifayi korubo ifa ni ko mo fiinu re taneniyankomo fiinu han orere ifa ni oun ati enikan won njori papo ifa peeniyanko feranre korubo komo ba daran bo lorun
Ifa pere fun enitoda ifayi ko mope ti fa o si o ifa ni orore otida ojoyu ko rubo ki orore o le ba dayo ko si mo fi ebo yi se alo ki o teleru ebo ni o
Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo ki o le ba la ko si mo gboju leogun etutuni ko mo se ni gbo gbo igba ko si fi atare kin ebo ru
Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo nitori ija oogun ifa si ni ko sora nipa obinrin papa lodo awon iyawo re ki won o mo ba fun ni oogunje ifa ni ti eleyi ba nda oko tin inkan ba nun ninu oko re ko mo wa kosi mo sepe eni tin ji inkan re yi ni o fayo ninu ewu ti ko ba si da oko ti inkanm re ba nun komo sepe o
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ibikan leleyi tin sise pe kio mun enu lele kiire re o le tolowo ifa pe eni kan o wa gburo pe ibeni tin sise ifa ni enina yowa ba pe ki awon o jomasise nibe ifa ni kogbafun pe ola wa nibe.
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo nitori iku ifa pe eleyi sun orunkorun oun lalakala ifa pe apere iku mo korubo
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo ifa pe oju ire gbogbo ni pon eleyi ifa ni ko si mo tete jiki ifami afejumo ifa ko simomun oju to oun pe ko moju toun to.
Ifa pere fun eni to da ifa yi ifa ni ti eleyii ba sise lode enikan korubo kole ba se aseyori nibe ifanmi eleyii osise bierin ojeijeeliri korubo si enu isere ko boogunni ewa eyan esun isu obi emun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
EyeleAkuko adie
Opolopo owo
Oruko
Opolopo owo
Akuko adieEyeleOpolopo owo
TARNSLATION
Ajugbuduru
Adivinacion de ifa paraOrunmilaQue dejara a su tesorero en la tierra Y subira al cielo
Se le pidio que ofreciera el sacrificio Y el cumplio
Por lo tanto, ajugbuduru ope no olvides traer contigo la riqueza de la bendicion que dije que esta por llegar. Ifa ajugbuduru ope no te olvides de traer contigo.
La bendicion de la nueva esposa que dije que aun no ha llegado.
Ifa ajugbuduru ope no te olvides de traer contigo.
La bendicion de dar a luz que dije que esta por venir.
Ifa ajugbuduru ope no te olvides de traer contigo.
La bendicion de toda la bondad que dije que esta por venir.
Akuko adie
Agbeboadie
Eyele
Esun isu
Ewa eyan
Obi
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Sese fun abi erin siki siki
Adifafun ara
Tii se omo Olodumare
Igba tin torun bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni ounpere ola oun pe AJE ifani ki won o da omo kan mo ti won orubo fun ifa mi olorire omo ni oloki ki omo sini kiwon o bo AJE ni ekuru funfun pelu eran tiko legun opolopo ogede omini
Ifa pere fun eni to sa ifayi ifa ni eni kan niyi tofeda opun ati oloro rekan po korubo ko dfi ewan kun ebo ru.
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni awon ota po fun eleyi ko rubo ko le ba segun won ifa ni ko fi ikode kun ebo ati iyeagbeiye aluko ki won o si fi se fa fun
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa pe ire gbogbo loun fofun eleyi ifa in oju oje n pon eleyi ifa ni korubo ko fi asarobo ifa
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Odidi lili eye kan ori gbigbe die etu ibon gidi die odidi atare kan ao jo po ti o bajo tan ao lo ti yo kunna ao wa da si meji ao mu idakan ao po mo ose ao ro ikeji sinu ado ato ao fi oti lo ti aba lo tan ao bu ose ao lo fi we
Ewe imi esu, ewe biotuje funfun epo obo eedu oju aaro ao gun gbogbo re pomo ose ao lo gbeeju sinu okunkun ao ma bu ni be fiwe larolaro
Kindinrin malu kan ao ge si merindinlogun je(16) iyere merindilogun (16) yanran okun ganrrin osa ao lo won pao mo igbo mimundie afi se kindinrin lepo niyo ao se adua si ao je ni oru nidede ago kan
Odidi eye etu kan iyeagbemeji iye aluko meji ikode meji aojo po mo arawon ao wa p0o mo ise ao ko sinu ike funfun ao ma fi we pelu kan hin kan hin tutu laro laro.
Ewe oju oro osi bata abere omi okun yanrin okun yanrin osa eru Alamo ao gun gbogbo re po mo ose ao fi omi okun po ao ko sinu ike funfun ao ma fiwe laro laro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe ina ewe segun sete erwe saworepepe ewe abiri kolo ao gun po mo ose ao ma fi we laro laro.
Iyeagbepupo iye aluko pupo ikode pupo odidi atare kan ao jo po mo arawon ao fi sin gbere lati iwaju ori de ipako
Ewe imi eran eru Alamo ako okuta were mesanh ao gun po mo arawon ao wa po mo ose funfun ati o se pupa ao mo fi we laro laro.
Explore Ifa
Ogunda Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Ogbe,Ogunda Oyeku,Ogunda Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Obara Odu.
