O
This Odu signifies the strength of character and the wisdom to navigate challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Leke leke ni oye dudu
Agbigbo ni oye tie ni funfun
Eye nla abi fora agajigi legan
Adifafun tela roko tiya tokola wale bioba ereke Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, isetan temigbayi
Telaroko mojiwo loko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ki elelyi orubo ni tori aje kosi ma se ose fun ifa dada ki I re aje ole ba defun
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ko rubo ifa ni oju ajo pon ifa ni ko fi oti bo fa ko si gba oti naa lawinni ko gbodo fi owo lara leyin toba bofa tan ni kolo san owo naa.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Bioguniyan sinu awo esun
Eni toyo lanan oluware ni oyo
Bi a roka sinu epo epa eru toyo lanan oluware ni o yo
Adifafun aduke omo afi olele disa eku
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifape ire fun eni to da ifayi ifa ni koma nisurupe ire nbo fun ko ma ma binu ko ma ko egin ifa ni to ba rin irnajo pe kolo sugbon gbogbo oun tobari nibe ko gbodo fise ibinu
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ifani korubo si enu isere ifa ni awonkan nso lenu isere bi won o se mun ifa ni ti babare banbe laye komo ki laro laro koto losi enu ise ti ko ba si babare lare laye kobo babare ifa ni ori baba ni oyoninuogunomo araye.
Ifape ire fun eni toda ifa yi ki osi rubo ki ire ola bato lowo ki osi ma jinnna si oso babare tori ire wa fun nibe.
Ifa pe ire fun eni toda ifayi korubo ifani irinajo kan ni elleyi felo korubo ko le ba ko re bo nirinajo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Omo ni dindinrin awo ori
Lodifa fun ori
Ori sawo lo ajule oloro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki elleyi o rubo ifa pe oun pe ire aiku fun oun si pere omo ko figbin ku eboru
Ika pe ire fun eni toda ogbe sa ifa ni ki orubo peawon omo araye nro laropin
Ifa pe ire fun eni toda ogbeka ki elelyi orubo ifa ni ounpe ire aiku fun ifa ni ko ni bawon kuku owowo
Ifa pe ire fun enmi toda ifayi ifa pe ire omo fun ko sibofa ni ije imun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin
Akuko
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo owo
Oruko kan
Akuko
Opolopo owo
Eku eja aboadie opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Agongo sigo
Agongo sigo
Adifafun ogunda
Ti yoo teyin wa borogbo mole
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elleyi o rubo nitori ola ifa ni ounpe ireaje fun leleyi korubo kire aje ole bade fun
Ifa pere fun eleyii, pe ebo ni ko o ru yoo sila ti yoo lu lenu ise re, sugbon ki o ma ni okanjua.
Ifa pe ire fun eni toda agbeka korubo ni tori aje ki aje ola ba to loowo ko si ekuru funfun bo aje ko si rubo kole bani isinmi
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ifa ni oju omo upon elleyi korubo yo di olomo laye ko fi agbebo ad bo fa.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe okika efunosunaojo po mo arawon ao ro sinu ato ao pa akuko kan si ao ro ejere si ao ma fi oti sinabu lo larolaro.
MEDICINE TRANSLATION
La hierba de okika, efun sustancia blanca en polvo,osunla sustancia roja en polvo se mezclara y se derramara en un guardia medicinal matara a un gallo y le arrojara toda la sangre y uno se la llevara con vino shinarp todas las mañanas.
Ewe oju oro osibata obere omi okun yanrin oku yanrin osa eru Alamo ao gun gbogbo re ponmo ose omi okun yi lao fipo ao kosinu ike funfun ao ma fiwe laro laro
Ewe rekureku ewe ogo ewe omini ao jo po ao ro si ibi kan ao ma fi oti lo larolaro.
Ewe ominsin minsin ita kun ao lomo iyere ao fi se eyin adire merin leponiyo ao fiyerosun te odure.
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe emun, igi ti sangopa aojo po mo odidi atare kan ao fisin gbere kan si arin ori.
MEDICINE
Ewe imi eran eru Alamo ako okuta were mesan ao gunpo mo arawo ao wa pomo ose ao ko si ori okuta ako kan ao ma fiwe.
MEDICINE
Ewe idi, odidi atare kan ao jopo ao ma fi omitutu lo larolaro.
Tangiri odidi kan opolo aye kan ao jo po mo odidi atara kan ao ma fi fo eko tutu mnu laro laro.
MEDICINE
Explore Ifa
Ogunda Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Oyeku,Ogunda Iwori,Ogunda Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Ogbe Odu.
