O
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Inanimunrinpon eyin ni o fibi eeyi rodorodo wole
Igba ewuro lokoro jogbojogbo bioroo
Adifafun lebe
Tii waya rasan rokun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki elleyi olomojuto ifa dada ifa ni yio je ki oniyi lawujo gbere ki omon fi ifa sere
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Yio fi elede bofa
Yio fi oruko rubo
Yio fi eyeetu bori
Epo
Eko
Obi
Oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ogunda se ori eku ni peku wa
Ogunda se ori eja ni n paja wa
Ogunda se ori eran ni n peranwa
Adifafun baba o para iragaja
Ti n momi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ki o lo bogun dada (aja)
Akuko adie
Epo
Eko
Eyeetu ni ori gba
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Igbo nla ni o se di awonka
Adifafun olubojo
Tii se awo rode ila
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire isegun Fun eleyi ki orubo isegun pelu awon ti ngb eogunti gbogbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Agbebo adie meji
Fun ifa pelu
Okete kan fun awon
Agbalagba
Oruka owo
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ogunda lawo alase
Ela roro lela tosumore
Adifafun lebe tiwa mola san rokun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi
Oru bo ntori ire
Gbogbo
Ifa pe ire gbogbo won
Eleyi korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemerin
Agbebo adie meji
Akujko adie meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ori oka kan
Ori re kan
Lekeleka kan
Ao jo pelu atare kan
Ati ewe sefunsefun
Ao lo kun na daa (ose ogunda)
Explore Ifa
Ogunda Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Ogbe,Ogunda Oyeku,Ogunda Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Ose Odu.
