O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ibiti eleyi
Nlo yi ki o rubo sibe
Ki omon fi oju di pe
ko sewu ki omon de
owo lasasan ni yio munbo
ibiti obalo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku, eja, eye, eran
Akuko adie meta
Agbebo adie meji
Epo ati eko
Ose monsa
Ose moo sojo
AdifafunorunmilaNjo ajogun ka
Baba mon le pitipiti
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje ose mon mon saOguno ti le koko
Ifa peki eleyi
orubo ki nkan
ti o le ro ko mon jepe nni yio mon da lamun ki osi mon fi ti ifa seyin ni gba kooka
Oruko
Akuko adie mejiEyelemeji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Patako abeyin monta monta
Adifafun ose oun Osa
Nijo won njija Agba lo si otu ife rere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki eleyi
o mon se oyaju
si eniti ojulo rara
ki ofi owo fun
eni ti ojulo ki
omo leyin ti e naa
le beru re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eyeetu mejieyelemeji
akuko adie meji
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ewe patanmon ewe alupaida ao lo papo ao fi se eyin ibile mejo lepo niyo pelu iyere ao te iyereosunno odun ifa (ose osa) ao se isure si dada
Explore Ifa
Ose Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Osa Odu.
