O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ija agbalagba meji ni owo papo Adifafun opolo oun efon
Nijo n won jija agba lo si otu ife rere EBO ni won ni won ose opolopo nikan nibe leyin ti
ntubo
Riru ebo
Eru atukesu
Eyin ori ifa awo ki biti nse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki eleyi orubo
nitori enikan nbe ti oju elelyi lo
ti nba fi aga gbaga papo if ape
ti o bale rubo nbe dada yio pada fiogbonsegun eni na
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran efon
akuko adie meji
agbebo adie emjieyelefunfun meji
epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ose turu
Ofi ipon gba di
Adifafun agandi
Ti nmon omi oju
Sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe eni kan ni
ti nwa omo ifa pe
lowo lowo bayi nse
nkan osu lowo
Ifa peko rubo
Ifa peasiko omo re tito
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Adie aga da
obi ati oti
Akuko adie mejieyelemeji
epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ose turu
Ipon turu
Adifafun oluigbo
Igbati nmomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki elelyi
orubo ntori omo
Ifa pe oun wa omo
Ifa peoun ni oun
o fun ni omo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure kan
Oti ati obi
Akuko adie mejiEyelemeji
Pepeye meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
odidi okete kan ao da inu re
lu ao ro ewe abo si dada ao
wa fi atare si ao jo papo
ao lo kunna dada
ao te odu ifa (ose turupon)
Explore Ifa
Ose Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Oyeku,Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Oturupon Odu.
