O
This Odu signifies the importance of adaptability and foresight in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osemin masesan
Adire damin loogun
N o foleyin
Adifafun alabahun tounOrunmilajo n sota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eni yii pelu enikan jo n sowo po, pe ebo ni ko ru komani ota re ni ko fe ki eleyii o sorire, sugbon eleyii yoo sorire, ebo ni ki o se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Eja meji
Abodie kan
Akuko adie kan
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ibi lebelebe eti aso leema wa
Adifafun yeepe
Ti yoo gbara re ti yoo gbagi oko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ke eleyii o rubo pe aarin ota ni eleyii wa, pe ko rubo oun yoo gba eleyii sile lowo awon ota re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewe yeepe lopolopo
Akuko adie kan
Epo
Eko
Maiz
Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Pabutu yeke
Adifafun jesu
Ti n tode orun bow aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo pe yoo la ti okiki re yoo si kan kaa kiri gbogbo aye.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Amala ati obe ohunla
Eku meji
Eja meji
Obi meji
OtiEyelemeji
Epo
Eko ati Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Pabutu yeke okun kan leru
Adifafun Aje
Igba ti n tode orun bo wa sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni aje n bo fun eleyii lenu ise re, pe eleyii yoo la ti gbogbo aye yoo si mo on.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igba olomori kan
Akuko adie kan
Epo
Eko agbado
Owo.
Explore Ifa
Owonrin Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori,Owonrin Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Ogbe Odu.
