Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Owonrin Ogbe

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of adaptability and foresight in overcoming challenges.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/owonrin-ogbe
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Osemin masesan Adire damin loogun N o foleyin Adifafun alabahun tounOrunmilajo n sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eni yii pelu enikan jo n sowo po, pe ebo ni ko ru komani ota re ni ko fe ki eleyii o sorire, sugbon eleyii yoo sorire, ebo ni ki o se

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji Eja meji Abodie kan Akuko adie kan Epo Eko Agbado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ibi lebelebe eti aso leema wa Adifafun yeepe Ti yoo gbara re ti yoo gbagi oko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ke eleyii o rubo pe aarin ota ni eleyii wa, pe ko rubo oun yoo gba eleyii sile lowo awon ota re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewe yeepe lopolopo Akuko adie kan Epo Eko Maiz Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke Adifafun jesu Ti n tode orun bow aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe yoo la ti okiki re yoo si kan kaa kiri gbogbo aye.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Amala ati obe ohunla Eku meji Eja meji Obi meji OtiEyelemeji Epo Eko ati Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke okun kan leru Adifafun Aje Igba ti n tode orun bo wa sile aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni aje n bo fun eleyii lenu ise re, pe eleyii yoo la ti gbogbo aye yoo si mo on.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba olomori kan Akuko adie kan Epo Eko agbado Owo.

Videos

Watch Owonrin Ogbe teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori,Owonrin Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Ogbe Odu.