I
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ikawori
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE KINI
(1)
Ika fefe lafoye
Iwori fefe lafogba
Adifafun ewiri ti se obinrinOgunIgba ti n fomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori omo ki o lobo ewiri agbede pelu akuko adie ati obi pelu oti
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Agbebo adie mejiEyelefunfun meji
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni poki are de o Ojonleke AdifafunorunmilaBaba o fi oro gbogbo se erinrin Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje poki are deo
Ojonleke
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon mon binu si gbogbo oro ti won ba so fun ki nkan re ole mon da.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeta
Akuko adie meta
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
(3)
Ikafefe la foye
Iwori fefe la fogba
Adifa fun oniyan hanyan
Ti ntorun bow a saye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o lobo ori re dada tio ba si ti ji ko mon sure fun ori re larolaro ko mon toro nkan to ba fe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etumeji
Pepeye meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
(4)
Ika fefe la foye
Iwori fefe la fogba
Adifafun agidingin
Ti won n ran se ilku pe lorun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori iku ko fieyelemerin se irapada emi re nipase alakala ti n la
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemerin
Ko fi igbin bo orisa
Akuko adie meji
Agbebo adie fun
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe okirika merindinlogun ewe tete adayeba merindinlogun eyo iyere merindinlogun aolo papo ao fi seeyeleti a ge si merindinlogun je ao tee fun ni odu ifa ikawori ao se adura si ao ko je pata pata
Explore Ifa
Ika Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ikawori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Iwori Odu.
