I
Ika Meji in Ifa Divination symbolizes caution, introspection, and the consequences of past actions.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ikameji
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Lopelope ejika ni kojewu obo
Lopelope kari baba rere bini lomon
Adifa funorunmilaIfa bi fagbemi sile
Ifa o bi fagbemi soko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun pe ire gbogbo fun eleyin ebo ni kose ko si dimon ifa daradara kosi bo orire pelu akuko adire kkan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire mejiEyelekan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kawo funni
Ki emi naa okase fun o
Adifafun onika mogun
Omo arakika kawo iku ko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun pe ire isegun fun eleyin ki orubo ki ole basegun kio si lo fi akuka bori ati tori isegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran akinka meji
Epo
Eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Okarakara oju kangara
Okanjua agba ni n woke radi radi
Ejo ni o komo ti eleyin yoyo kari oko
Adifa fun kerenulesin
Eyi ti yoo gboo gboo
Eyi ti yoo too too
Eyin tiyo lo egberindinlogun laye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo eni gungun ki eni re ole ba gun ti osi lo fi okete kan bo orire.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Okete aye kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kawo funmi kin
kase fun o
Adifa fun ode
Ti n sode re gboje eluju je
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun pere fun eleyin ni okere sun gbon ki omon lo inu meji tori ki ire na ole ba to lowo kio si lobogun pelueyelemerin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemerin
Akuko adie kan
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao wa ewe sajeje ewe okika ao fi se eran aki ka je ni epo ni yo awon ohun ti abaje kan ni be ao gun monose dudu eni naa yio maafi we.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ewe gbegbe ati ori ejo ao wa jopo eni naa yio fi sin gbere larija yio fi iyoku joko ninu fun ojo meta.
Explore Ifa
Ika Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ikameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori,Ika Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Meji Odu.
