Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Ika Odi

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents perseverance and the resilience needed to overcome obstacles.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ika-odi
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE KINI 1 Kala nkan di Adi kaka wolu AdifafunorunmilaBaba ngbogun lo si ibi atoketodoke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ibi ti eleyi nlo yi if apeogunnbe nibe fun ifa pe korubo lo kole ba segun bo ibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko Akuko adie meta Agbebo adie meji Eku Eja Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ika dindi awo erin Adifafun erin Ika dindi awo efon Adifafun efon Awon ko niyi ebo Igbati won sunkun pe awon ko niyi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki awon omo iyameji tabi ore meji ko rubo ki won o le ba gbayi nibi ti won ban lo tabi lori nkan ti won ba dawo le

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelemerin Pepeye merin Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni akadi akadi Adikaka wolu ntoriogun ologunNijo ti n lo le ba won jagun igbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi orubo oun ti o fe dawole ki ole ba se aseyori re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie merin Eye etu merin Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Agborin o ni gege Awo ileorunmilaAdifafunorunmilaIfa nsunkun pe oun ko lowo lowo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ki eleyi o bo aje if ape eleyi nsunkun aje aje o joko ti eleyi to

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelemeji fun aje Igbin merin fun aje Obi Oti Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

1ISEGUN Eeso lowerenjeje eyo meje ao lo pelu eyo atare meje ao lo ti o kunna dada ao wate ni ikadi ao so gbogbo nkan ti aba fe ao wa fi sin gbere si orikerike ara

Videos

Watch Ika Odi teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Odi Odu.