Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Ika Okanran

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the journey of perseverance and strength in overcoming challenges.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ika-okanran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ika kankankan Bi ina eyin Olakanran kankankan Bi oorun owuro Adifafun ijobiona Tii se ojise irunmonle merindinlogun Eyin ijobi ona bi eba la tan Kemonse gbagbe awo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa sope oun pe ire ola fun elelyi amon ki eleyi omo Se okanjua ki ire naa ole to lowo Kio si fi akuko adire rubo pelu aso ododo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Aso ododo Eko Epo Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ika kankankan Babalawo agogo Adifafun agogo Agogo nbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa sope oun pe ire iyin fun eleyi pea won meji kan nu ti won ojodASE po ki won orubo ki aye ole bayewon ki won osi fi pepeye bo ori won

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Epo Eko Oni
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ika kankankan biina Eyin Olokanran kankankan Bi oorun awuro Adifafun ode ode nsawolo Igboje eluju je

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire gbogbo fun ore meji pe ki won orubo ki ire ole batewon lowo ki won ofi ewure bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran koro kara Adifafun ikakara Abu feja Nijo ti won gbogun lo ilodo Ebo ni won ni kiwon ose Won gebo ni be won rubo Nje, ikakara kosai beja gbodo ikakara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa so pe ire isegun fun eleyi ki elleyi olobo ori re pe awon kanni won fe gbogun ti elelyi ebo ni koru ko fi eyetu bo orire kio fi akuko rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyetu kan Akuo adire kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe ina ewe esinsin awo ilu ao wagon mo ose dundun ao wa lotoju okusu are ao wa fin po ose naa ao wa maa we larolaro.

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ori eye etu ati ewe tund e ati egbo re ao Wa jo tio bajo tan ao wa fi si gbere si orun owo Ati oru ese ao wa fi iyo Ku fo eko tutun mu.

Videos

Watch Ika Okanran teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Okanran Odu.