I
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Kasa ni abi kaja ni
Adifafun olugbo
Ti nlo lee ra ada leru
Won ni ko gbebo korubo
Igba aisebo
Igba aiteru
Eyin orifa awo ki biti nse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo lori nkan ti of era tabi nkan ti ofe se ki o mon je pe nkan naa ni yio mon gbogun ti.
Ifa pe ki eleyi orubo nitori peagbarare ko ka nkan tin se awon aye si npegan re, ifa pe ipare yi o ka aye.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Akuko adie meji
Epo
EkoEyelemeta
Eye etu meji
Oruka ti won nfi sowo meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Mo bawo
Mo ka wo
Adifafun ada
Ti ngbogun lo iluigbo
Ika awoetutuAdifafun ada
Ti n se awo lo ogba awo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Okete
Akuko adie meta
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ika sa
ika ba
Eyinkule nika we
Adifafun temi lese
Ti nrugba ipin kirin
Temi ese ese
Ise orimi ran mi
Ni mo nje kiri
Ika ko aturupon dere
Adifafun iba
Tise OmooduduaIgba ti ntorun bowa sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo isegun lori nkan ti o fe se ifa pe ire isegun fun
Ifa pe ki eleyi o mon juba fun awon ti won julo ki o si mon se afojudi si enikankan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Odidi ada kan
Akuko adie meji
Agbebo adie meji
Epo ati eko
Akuko adie metaEyelefunfun meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ika tuwo
Ipon tu se
Adifafun olongo
Ti se elewu iyi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o mon sun orire loro mon ki osi mon bo ori re dada ifa ni ori re ni o se gbogbo nkan to base fun
Ifa pe ki eleyi o rubo iyi ki o le mon gbayi nibikibi ti obalo ki aye le mon fe tie
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ogbe ori akuko ti won fib o esu ori eye etu ti won fi rubo odidi atare kan pelu egbo ope Ifa a o jo papo ao te ni ika osa a o se adura si Abe Olukondo ni won o fi sin gbere na si orikerike ara A o mon fi iyoku fo eko tutu mun.
IRE AJE
Ewe itebi ewe damonto ao gun papo mon iyere ao fi se alahun kan lepo ni yonje ao te iyere osu ni odu ifa IKA oturupon
Explore Ifa
Ika Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Osa Odu.
