I
This Odu emphasizes the importance of strategic planning and thoughtful decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ika Otua
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ika gburo Adifafun aparo Oyeye tolo nje Alagburo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo lori nkan ti o fe se ki o le ba se ase yori lori re ko mon je pe enu nikan niyio mon fi mon se gbogbo igbesi ayere
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie mejiEyelefunfun meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Omi tokitoki
Abe eruwa
Adifafun
Alakan
Abufun eja
Iku oni yale eniti nrubo
Ero ona oniyale
Alakan komunmi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki awon omo iyameji kan o rubo ki won ole mon se aseyori ki won osi rubo ki ajogun buruko o mon wole won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Akuko adie meji
Opolopoomi tutuEpo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
IFA NI KAKA TUA
Kaka tua
Adifafun aparo
Oyeye to ni oun
Osawo losi ode ilora
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe nkan ti eleyi o ba ni se ko mon so pe oun ose fun eeyan ko mon se adehun ti ko ni mun se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete
Opolopo epo pupa
Igbin mejo
Epo
Eko
Pelu owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ika tuatua
Babalawo enu
Adifafun enu
Enu nbe laarin
Ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ki eleyi o mon so roro buruku jade lenu ki o mon nkan ti oun o mon so sita nitori ase nbe lenu re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie metaEyelefunfun meta
Abere oporo meta
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
IRE ISEGUN
Ikarahun igbin ti a fi rubo ao jo pelu ewe apaagun mole ao fi abere ti afikun ebo ru yi sin gbere si orikerike ara wa ao fi ebu ifa ra daadaa ao mon fi iyoku mun oti oyinbo
Explore Ifa
Ika Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ika Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Otura Odu.
