I
This Odu emphasizes the importance of embracing change and new beginnings.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ika Yeku
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE KINI
(1)
Alakaiku ni Baba erin
Odoromun ni Baba efon
Odoromun ni o gbe
Alakaiku mi terin terin
Tile kudi tilekudi
Toun tapo alukurani
Toun tapo alukurani
Adifafun oosala oseremongbo
Igbati nti irenje ile losi
Irenje oko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi olo bo oosa dada ole yori si rere
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo igbinEyelefunfun meta
Akuko adie meta
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
(2)
Alakaiku ni Baba erin
Odoromun ni Baba efon
Odoromun ni ogbe
Alakaiku mi
Terin terin
Adifafun ori nigaga ingogo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon bo nipa gbogbo dada nipa gbogb nkan ti o ba fe dawo le
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meta
Pepeye meji
Agbon
Eyetu kan
Pelu obi ati oti
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
(3)
Oke le gege monye
Adifafun onikayekun
Igbati nfomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi orubo ntori omo ki osi gbo ikilo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Akuko adie mejiEyelemeji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
(4)
Irun pe lori
Irun di ewu
Egbo perese adi
Jakute
Adifafun alakaiku
Igbati nbe laarin osiri
Ti nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo isegun ota ki ifa oba segun awon ti ngbogun ta bo ko ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Obi fun ori
Orogbo
Oti
Akuko
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori ologbo meji ewe adagudu topo dada odidi atare meji Totobi dada ao jo papo ao teni odu ifa ikayeku yio mon fi
foko Tutu mun tabi oti schnapps leyin ti ati se adura si tan dada.
Explore Ifa
Ika Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ika Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ika Meji,Ika Ogbe,Ika Iwori,Ika Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Oyeku Odu.
