I
This Odu signifies the power of transformation and strategic planning.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ika
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ateka Awo ila
Lodifa fun Ila
Ateka awo ikan
Lodifa fun ikan
Adifa fun bobo awodi
Nijo tawon mete eta n tode orun bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon meta ni ki won o man rubo sugbon eyo eni kan ni yio rubo oun ni kan ni yio segun kele yi osi rubo fun omo re kawon ota oman man pa omo ele yii.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ilasa Te Gbegbe ni won
Iwo nikan kobe
Adifa funorunmilaBaba nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon ota n wo eleyi ni wo koku koku sugbon korubo yio segun paa paa julo awon ota ti ro eleyi pin wipe kole jen kan kan laye man sugbon ki eleyi orubo ni soju awon ota nan ni eleyi oti la .
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oku Ita Oberu Okunkun
Adifa fajimokun
Tii somo oba orangun ode ila
Igba ti n fomi oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ire aje fun eleyi lenu ise re, ko si man fe bo salo, keleyi o si ma maa sun orire loro mo, kosi ma man febi para re, kosi man se aanu ki re aje re ole baa tete tee lowo .
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
OwoEyelemeji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Oku ita nii oberu okun kun
Adifa fajeolokunsannin ade
Igba ti n tode orun bo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo aje fe joko ti eleyii, ko si man bi nun kire ajere olejoko tii lati ara eleyi opolopo eeyan ni oti arare lai kosi man se oore.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
OwoEyelemeji
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUNEyeledudu kan opolo esuru pupa ewe ailu odidi atare kana o jo po ao man fi fo ko mun
Explore Ifa
Irete Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Ika. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Ika Odu.
