Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irete Iwori

Irete Iwori also known as Ifa Irete Iwori
Aliases:Ifa Irete Iwori
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of introspection and self-awareness.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irete-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Iwori

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Atepa Awori Babalawo Erin Lodifa ferin tin lo lee goke alo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo awon ota nda eleyi pada seyin, ibikan ree ti eleyi fee lo sugbon awon ota n di lowo won oje ki oroke tabi oore baba eleyi kan re awon ota ofe ki oto lowo Korubo kire eleyi o leto lowo Keleyi orubo amon ota koje ki eleyiosun, ki eleyii o rubo yio segun won, eleyii n la awon aala kan ti ko dara awon iko orun ni n won fe mu eleyi lo korubo kiwon o ma baa pa eleyii

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Ada kan Agbado Owo Epo Eko Agbado Akuko die kan Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Atepa Iwori Babalawo oba Lodifa fun oba Ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Awon ota nda eleyi laa mun won ojeki pa re oka oun tin da wole ti eleyi bati pa se bee ni awon ota nyi mun si eleyi won oje ki ose oun tolese sugbon korubo a pare oman ka oun toba dawole Keleyi orubo yio segun ota, keleyi o si fi ewure kan rubo eegun eyin eran yi ai fi kun ebo ru eje ara eleyi ao fi kun eboru nitori awon iko ti eleyin ri kadara korubo kole baa segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Oruka Agbado Owo Epo Eko Agbado Alabahun kan Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Atepa Awori Babalawo oba Lodifa foba oba Igba ti n fomi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ni tori oju ajenpon eleyii, pe ajenbo feleyi ki osi rubo senu ise re, yio la gidigidi kosi maa so ooto Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi ti gbogbo aye osi man wipe ajede feleyi ki eleyi obun awon oni lu lowo ko si man lo si bi ti won ba tin se ariya daa da ni be ni re aje re yio ti to lowo ko si man wo aso daa da

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko AgbadoEyelekan Owo Epo Eko AgbadoEyelemeji Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Epo lose je su Akaso lodun gaka Obinrin se barin jokunrin lo Adifa fun oosala osere mangbo Tin sun kun poun otoju bare

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyiorubo gbogbo oore eleyin lo ko yale re korubo kire olee yalere papa julo omore kan re ki won o maa borisa fun un, ori omo yii yoo man lanan fun baba re oore meji kan sin bo fun eleyi korubo leba do lomo Keleyi orubo daa da kaleyi ba se ru bo si bee ni re aje re yio se po to, ibikan si lele yin lo yi pe yio rire munbo keleyi osi man soro to dara lenu ni pa se bee ni re eleyi yio se telowo Ko si man bo aje daa da

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi igbin meji borisa pelu obi meji Epo Eko Agbado Abodie kan Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Isu ogiri sako eepo obo eeru alamo ao gun po man ose ao ti opolo aaye kan tele igba olomori ao ko ose lori ao man bu we ISEGUN Ao to ju ikoko kana so eleyi wo to fi dafa ao ko tele ikoko yi ao ko ewe peregun merindinlogun le lori eleyi yio fa omin fo orire si nu ikoko yi ao de pada ao lo bo man inun igbo

Videos

Watch Irete Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Iwori Odu.