I
This Odu represents the balance between wisdom and action.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Obara
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Iretente Olobara man ba man
Adifa fun sonjia
Tin be larin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo eleyi yio sib o egbere awon egbere ni oba segun keleyi osi ma maa safojudi ko man je pe ibe ni won o ti femu eleyi kosi maa ni iteriba fawon ti won julo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fin ekuru boegbeati obi meji
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Irentegbe Olobara Man ba man
Adifa fun Ehoro
Tin sore aala
Igba tin be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo yio segun otare ko si bori orere kan ori ore re yio ba segun nitori awon ota n lepa eleyi lati pa sugbon ori orere ni yoo la ti pa ota ofi ni kaa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi obi meji bori ore eleyi kan
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Irentete Olobara man ba man
Adifa funorunmilaBaba ji baba orowo kan aayo na
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Kileyi orubo aje n bo fun eleyi, keleyi osi fi opolopo ekuru fun ifa ati ori bo aje ati eyin sise won osi pe eleyi ni bi kan kotete je ipe ni tori ni be ni oti la
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Irentete Olobarta Man ba man
Adifa faje tii so moolokunesin eepe
Igba ti n tode orun bo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi ofi ekuru bo aje aje nbo wa joko ti eleyi ni tori lati ode orun leleyi ti yan re aje wa saye ni tori ni bi tire aje eleyi yio de aye oni ridi eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Eku ASINRIN kan ati ejo egbo ifan ao jo po man odidi atare kana o man fi fo ko mu.
Explore Ifa
Irete Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Obara. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Irete Meji,Irete Ogbe,Irete Oyeku,Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Obara Odu.
