Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irosun Irete

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irosun-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Igbaa nla abi oro tooto legan Adifa fun won ni mesin ejeru Nibi ti won tin peru legbon nitori omo Won ni won orubo Ki won le baa bimo Won gbebo nibe won rubo Ero ipo Ero ofa E wa bani laarin omo Aarin omo lawa wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ota nda laamu, ko fi obi bo rire, Ori re ni yio ba segun pe ayen da eleyi laamu, won o je ki eleyi ogberi, bi eleyi se n se wahala eleyi awon aye oje ki won oman eleyi sugbon asiko to ti eleyi osegun Keleyi orubo ibikan leleyin lo yi awon ota sope ko ni de korubo yio de ti oju osi ti awon ota re keleyi osi bo orisa oko orisa oko ni yio gba eleyi le lowo awon ota.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Opolopo abere Ori ejo Owo Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Igi ajuba ni nii jongojongo Adifa fun ogun O ngbe ogun lo igbomekun eseji Awoni korubo alo ati abo Ogun fi gbigbo salaigbo O ko ebo beni korubu O fi eti otun gbebo ofi tosi danu Nje sure wa elenini ngbe milo Gbogbo orisa sure wa Elenini ngbe milo Oko kai ori baba elenini baba wa Keepe Kee jinna Ifa de alase ope asise wara wara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ko bo orisa oko orisa oko ni yio ba eleyi segun Ni tori awon ota n wo ibi ti eleyi oba ja Sugbon eleyi o se gun ota re Keleyi osi man so oro enun re daa da. Keleyi orubo ire isegun ota feleyi lenu ise eleyi ogbodo lo si ibi ipade lenun loolo yii nitori awon ota ti mun ra le de eleyi ni pade keleyi osi ma maa binu lenu looloo yi kipa ota o man baa ka eleyi.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi obi meji bo orisa oko Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Olobiri koto lawo aweje wemun Adifafun olofin nife oun daye Won ni korubo komo se ojojo Ko mo towo eeri benu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ire aje nbo feleyi, kele yii osi bo eegun eleyi yio deni ti aye o man pesin awon oku orun eleyi yio la awon eleyi ko fi akara bo oku orun re nitori awon ni won oda ko irere wa fun Keleyi orubo ko si bori ore re kan yoo la lodun yi niu pooro oko ni eleyi yoo ti bori ore re nan, ori ore eleyi ni ola.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Eyele kan Owo Ao fi obimeji bo eegun Epo Eko Agbado Owo Ao fi agbon meji bori
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Adogboloko adogboloko Adifafun orunmila Won ni baba onirikin re bo mo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ire aje nbo feleyi ko rubo kosi bo fa nitori eleyi o gbare mun bi eleyi se n ri owo ko man bi se n tan sugbon keleyi o bofa kire eleyi o oleba mo duro lowo re Keleyi orubo ire aje koduro lowo re, ko rubo kire re ole ba duro lowo re keleyii o si bofa re pelu eku, eja abodie nitori orunmila ni oun yoo dako ire eleyi wa fun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi eku eja abodie obi meji bofa Epo Eko Agbado Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ao to ju ori ejo eyi ke yi oko atare kana o lo po ao fi sin gbere kan siwaju ISEGUN Awo ejo eepo obo ebo sile ko nun ko ho ao gun po mo se ao maa fi we

Videos

Watch Irosun Irete teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Irete Odu.