Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irosun Oyeku

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for balance and harmony to achieve success.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irosun-oyeku
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ejemu ni difa ori igi Akan ni teye tutu Adifafun Lanrubo Ti n somo ajaniwarun Igba tin raye alainiku e

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire fun eni to da ifa yi won orubo aiku fun omo to dibo ifa yii tabi ifa oun pere aiku fun eni to da ifayi ko lo fi akuko die bo ibo ifa ti won da.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Itakuta lanta aso irikuri laari ofii Adifafun igbin Ti n lo re wo ilero isu tuntun lodun Won ni ko rubo saiku arare O gbebe nibe orubo Nje eyin n isoro ope Aweku lefe wegbin ndahun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere aiku fun eleyi ko lo re te ifa ki see ati osi arare ko le ba kuro.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ota kinni sokin Arosunta kelekun Adifafun orunmila Baba o ta kedeyofidi akapore loju Yoo ni oun o marun ti n se oun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo ki ifa o maa ba se pada leyin re kio sib o fa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Akuko Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

ASE IFA Isale akitan ni roganje ganje Adifafun jegbe Omo ajegba rinmokun Ebo ni won ni ose O gbebo nibe orubo Ruru ebo Eru atuka esu E wa bani laiku gbanhin gbanhin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to dafa ifa korubo ifa oun pe aiku fun ko toju ipepe irun fi kun ebo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko Adire Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe tangiri (60) agun papo mo ose owo eyo ti ko loju (60) ao lo aopapo mo ose tia ba guntan a o wa pa eyele kan si a o ro eje re si ao po mo ao la eyele yi laya ao fi tele igba ao lko ose yi le ao fi ori eyele yi gun ose lori ojo aje lase ifayi ojo aje lao bere si ni we

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ipose adire, ipose eyele a o jo papo mo atare odidi kan a o fi ssin gbere yipo orun owo mejeji

Videos

Watch Irosun Oyeku teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Iwori, Irosun Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Oyeku Odu.