I
This Odu represents the need for careful planning and strategy.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Won debi
Won dare
Oke ni o diyan ega olayaja bi omo oruko
Adifafun Orunmila
Baba momi oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun o ba eleyii segun paa pa julo obinrin ni yoo segun fun eleyii, ebo ni koru , ko lo ree bori iyawo re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Omo odo meji
Iya odo meji
Oruko nla meji
Opolopo yangan
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa po oun pere fun eni toda ikayi ko rubo nitori arun kofi opolopo abe robo ati aso arare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Igbaabe
Aso arare
Opoplopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Agbon nije sibi kando
Irosun lawo ega
Adifda fun iyere ope
Eyi tiko lele mo
Ti n fowo ara mun igi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Eweogo ewe iranje ewe igbo ewe esisi ewe alukerese ao gun po mo ose ao fi lofinda bintu po ao kosi aso funfunti aran ni asunhan ao so kosi oke ko gbodo kanlemo
Eye ega merindinlogun (16) odidi atare kan aojo po ao fisin gbere merindinlogun (16) si ari ori
Explore Ifa
Irosun Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Obara Odu.
