Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irosun Odi

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irosun-odi
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Paa okun ni jamoju reefe Adifa fun olosun Ti won lorore onija diju

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire nbe fun eleyi sugbon awon aye o fe ma sele ni ni re Ifa ni ki eleyi o mo feran obinrin kankan lo elelyi yo si bimo meta kan, ifa ni awon omo yii ni wongbija iya won

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba eyele Eyele mejo Opolopo owo Gripia oruko Tabi akakuko adire meta Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Olo bodo gbele Olo komohun odo Amokisi won o mohun ekun Adifafun labe lapo Ti saya ekute Ti n tole diya olongbo ni gbeyin
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Irosun di lomode da Omokekere kida idi aisun Adifafun won nidin samu Won ni won o fi aporobori Won o le baa fo ju kan re Sinmi titi lawo sinmi titi Sinmejinan lawo sinmejinan O le sin mejinan koba mi dele irosun towon nifa Adifa fun oba alara yobe kinrin eye Yo be kinrin eye Yodemi kin kin si

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to dafayi korubo kole di olola kofi aparo bo ori tori ire ifa ni ire koni bo sonun lowo re Ifa pere fun eni toda ifa yii, ifape ninu awon eleyi oun fi oju kere eni kan fo. Oun foju pe ko lese inkankan fun oun tabi ninu awon orere ifa ni komo foju di eyan ifape eni kan n be tin ja eleyi logun korubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aparo Eyele Opolopo Owo Akuko adie Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Irosun di lomode da Omo kekere kiida idi aisun Adifafun orunmila Baba momi oju sogbere aje Ori keke awo ni Adifa fun iya lode ijayi Ti yoo rire meji meji loojo Ona gbooro Ona koo Adifa fun won nirosun elerin Won n fomi oju sogbere aya Igba nla abeekan niha Adifa fun orunmila Baba n sawo rele irosun towan nifa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi, ifa ni oju aje nipon eleyi korubo kio le ba ni aje Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ibi kan laleyi ninlo ko rubo kole kore bo nibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Opolopo owo Eyele Abo adie Akuko adie Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe sapo ewe ogede agbagba ewe saworopepe ewe ina epo konu koho tio babo sile funrare, ao gunpo mose ao fi lofinda bi tupo ao ko sinu ike funfun ao ma fiwe Omundun ewe pandoro ao lomopomo iyere ao fi se odidi igbin kan leponiyo ti oba jinnan ao su aso funfun ni o suka ao so kanoru ao se adun sini ihoho

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Egbo akerejupon mokanla ao jo odidi atare mokanla ao jo pomo arawon ao fi sin gbere meta meta si orikerike ara Ewe sereyo egbo eti pon ola epo obo die odidi atare kana o jo po ao wa fi sin gbere yipo orun owo mejeji

Videos

Watch Irosun Odi teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Odi Odu.