Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irosun Ose

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irosun-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Adako pebu apajuba kan odo Adifafun ajibola tii se ore aroni Igba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa sope ota fun eleyi ko rubo ko bale segun won ore kan wa fun eleyi peota nikorubo ko le sugun won

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Egungun ileyi oso Eniyan be kiki ika Adifafun ofaafa Tiyo ye eyin tie sarin igbe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyi ko rubo fun aye awon nda lamu won o jinna si korubo kole ba segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire Pelu opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Eegungun ileyi kiki oso Osa ileyi kiki aje Adifafun otosi odo Ti o mo singba lorun Yoo mo gbade bori

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to da yi ko si rubo gbese, ifa ni eleyi jegbese ko si rubo kolebo kole baje gbe kosi rubo ola

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Akuko adire Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Agbara ni o gbaya iun ogan baje Adifafun abo ifa bole nitori omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni todayi ifa ni oju omo nip on eleyi korubo ko sib o ifa ati ile

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abodie Opolopo ekuru Opolopo eko Oti Opolopo obi Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Odidi lekeleke kan ori eye kan ori agbigbo kana o jo po ao po mo ose ao ko siunawo funfun ao ma fiwe ni afejumo laisoro si eni kan kan

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Egbo ologunsese egbo ipin ao jo po mo odiid atare kan ao fi sin gbere si arin ori meje ni ao sin

Videos

Watch Irosun Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Ose Odu.